Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 10:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn eṣú náà yóo sì bo gbogbo ilẹ̀, tóbẹ́ẹ̀ tí ẹnikẹ́ni kò ní rí ilẹ̀ rárá, wọn yóo sì jẹ gbogbo ohun tí ó ṣẹ́kù tí yìnyín kò pa, wọn yóo jẹ gbogbo igi rẹ tí ó wà ninu pápá oko.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 10

Wo Ẹkisodu 10:5 ni o tọ