Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 10:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Mose bá gbé ọwọ́ rẹ̀ sókè sí ojú ọ̀run, òkùnkùn biribiri sì ṣú bo gbogbo ilẹ̀ Ijipti fún odidi ọjọ́ mẹta.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 10

Wo Ẹkisodu 10:22 ni o tọ