Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 10:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ jọ̀wọ́, ẹ dárí ẹ̀ṣẹ̀ mi jì mí, ẹ bá mi bẹ OLUWA Ọlọrun yín ní ẹ̀ẹ̀kan ṣoṣo péré yìí, kí ó jọ̀wọ́ mú ikú yìí kúrò lọ́dọ̀ mi.”

Ka pipe ipin Ẹkisodu 10

Wo Ẹkisodu 10:17 ni o tọ