Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 10:1 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA bá pe Mose, ó ní, “Wọlé tọ Farao lọ, nítorí pé mo tún ti mú ọkàn rẹ̀ le, ati ti àwọn ẹmẹ̀wà rẹ̀, kí n lè ṣe àwọn iṣẹ́ ìyanu mi láàrin wọn.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 10

Wo Ẹkisodu 10:1 ni o tọ