Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 7:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Yóo fẹ́ràn yín, yóo bukun yín, yóo sọ yín di pupọ, yóo bukun àwọn ọmọ yín, ati èso ilẹ̀ yín, ati ọkà yín, ọtí waini yín, ati òróró yín; yóo bukun àwọn mààlúù yín, yóo sì mú kí àwọn ẹran ọ̀sìn yín kéékèèké pọ̀ sí i, ní ilẹ̀ tí ó ti búra láti fún àwọn baba yín.

Ka pipe ipin Diutaronomi 7

Wo Diutaronomi 7:13 ni o tọ