Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 7:12 BIBELI MIMỌ (BM)

“Bi ẹ bá fetí sí òfin wọnyi, tí ẹ sì pa wọ́n mọ́, OLUWA Ọlọrun yín yóo mú majẹmu tí ó bá àwọn baba yín dá ṣẹ lórí yín, yóo sì fi ìfẹ́ ńlá rẹ̀ hàn yín gẹ́gẹ́ bí ó ti ṣèlérí fún wọn.

Ka pipe ipin Diutaronomi 7

Wo Diutaronomi 7:12 ni o tọ