Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 5:22 BIBELI MIMỌ (BM)

“Àwọn òfin tí OLUWA fún gbogbo yín nìyí, nígbà tí ẹ fi péjọ lẹ́sẹ̀ òkè, tí ó fi fi ohùn rara ba yín sọ̀rọ̀ láti inú iná ati ìkùukùu, ati òkùnkùn biribiri. Àwọn òfin yìí nìkan ni ó fun yín, kò sí òmíràn lẹ́yìn wọn, ó kọ wọ́n sára tabili òkúta meji, ó sì kó wọn fún mi.

Ka pipe ipin Diutaronomi 5

Wo Diutaronomi 5:22 ni o tọ