Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 5:21 BIBELI MIMỌ (BM)

“ ‘O kò gbọdọ̀ ṣe ojú kòkòrò sí aya ẹlòmíràn, tabi ilé rẹ̀, tabi oko rẹ̀, tabi iranṣẹkunrin rẹ̀, tabi iranṣẹbinrin rẹ̀, tabi akọ mààlúù rẹ̀, tabi kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ rẹ̀, tabi ohunkohun tíí ṣe ti ẹlòmíràn.’

Ka pipe ipin Diutaronomi 5

Wo Diutaronomi 5:21 ni o tọ