Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 5:16 BIBELI MIMỌ (BM)

“ ‘Bọ̀wọ̀ fún baba ati ìyá rẹ gẹ́gẹ́ bí OLUWA Ọlọrun rẹ ti pa á láṣẹ fún ọ; kí o lè pẹ́ lórí ilẹ̀ tí OLUWA Ọlọrun rẹ fún ọ, kí ó sì lè máa dára fún ọ.

Ka pipe ipin Diutaronomi 5

Wo Diutaronomi 5:16 ni o tọ