Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 5:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Ranti pé, ìwọ pàápàá ti jẹ́ ẹrú ní ilẹ̀ Ijipti rí, ati pé OLUWA Ọlọrun rẹ ni ó fi agbára rẹ̀ mú ọ jáde. Nítorí náà ni OLUWA Ọlọrun rẹ fi pa á láṣẹ fún ọ láti ya ọjọ́ ìsinmi sọ́tọ̀.

Ka pipe ipin Diutaronomi 5

Wo Diutaronomi 5:15 ni o tọ