Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 4:32 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ẹ lọ wádìí wò bí ó bá ṣẹlẹ̀ rí kí wọ́n tó bí yín, láti ọjọ́ tí Ọlọrun ti dá eniyan, ẹ wádìí káàkiri jákèjádò gbogbo àgbáyé bóyá irú nǹkan ńlá báyìí ṣẹlẹ̀ rí, tabi wọ́n pa á nítàn rí.

Ka pipe ipin Diutaronomi 4

Wo Diutaronomi 4:32 ni o tọ