Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 4:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí pé, aláàánú ni OLUWA Ọlọrun yín, kò ní já yín kulẹ̀, kò ní pa yín run, bẹ́ẹ̀ ni kò ní gbàgbé majẹmu tí ó fi ìbúra bá àwọn baba ńlá yín dá.

Ka pipe ipin Diutaronomi 4

Wo Diutaronomi 4:31 ni o tọ