Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 4:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀yin náà ti fi ojú yín rí ohun tí OLUWA ṣe ní Baali Peori, nítorí pé, OLUWA Ọlọrun yín pa gbogbo àwọn tí wọn ń bọ oriṣa Baali tí ó wà ní Peori run kúrò láàrin yín.

Ka pipe ipin Diutaronomi 4

Wo Diutaronomi 4:3 ni o tọ