Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 4:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ kò gbọdọ̀ fi kún òfin tí mo fun yín yìí, ẹ kò sì gbọdọ̀ mú kúrò ninu rẹ̀, kí ẹ lè máa pa òfin OLUWA Ọlọrun yín tí mo fun yín mọ́.

Ka pipe ipin Diutaronomi 4

Wo Diutaronomi 4:2 ni o tọ