Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 33:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó súre fún ẹ̀yà Nafutali pé:“OLUWA ti ṣíjú rere wo Nafutali,ó sì ti bukun un lọpọlọpọ,ilẹ̀ wọn bẹ̀rẹ̀ láti adágún Galili,títí lọ kan gúsù gbọ̀ngbọ̀n.”

Ka pipe ipin Diutaronomi 33

Wo Diutaronomi 33:23 ni o tọ