Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 32:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣé irú ohun tí ó yẹ kí ẹ fi san án fún OLUWA nìyí,ẹ̀yin ìran òmùgọ̀ ati aláìnírònú ẹ̀dá wọnyi?Ṣebí òun ni baba yín, tí ó da yín,Tí ó da yín tán, tí ó sì fi ìdí yín múlẹ̀.

Ka pipe ipin Diutaronomi 32

Wo Diutaronomi 32:6 ni o tọ