Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 32:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn ẹ̀yin ọmọ Israẹli ti hu ìwà aiṣododo sí i,ẹ kò sì yẹ ní ẹni tí à bá máa pè ní ọmọ rẹ̀ mọ́,nítorí àbùkù yín;ẹ̀yin ìran ọlọ̀tẹ̀ ati ẹlẹ́ṣẹ̀ yìí.

Ka pipe ipin Diutaronomi 32

Wo Diutaronomi 32:5 ni o tọ