Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 31:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Mose bá pe Joṣua, ó sọ fún un níwájú gbogbo àwọn eniyan Israẹli, pé, “Múra gírí, kí o sì mú ọkàn gidigidi nítorí ìwọ ni o óo kó àwọn eniyan wọnyi lọ sí ilẹ̀ tí OLUWA Ọlọrun ti búra fún àwọn baba wọn pé òun yóo fi fún wọn. Ìwọ ni o óo sì fi lé wọn lọ́wọ́.

Ka pipe ipin Diutaronomi 31

Wo Diutaronomi 31:7 ni o tọ