Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 31:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ múra gírí, kí ẹ sì mú ọkàn gidigidi. Ẹ má bẹ̀rù rárá, ẹ má sì ṣe jẹ́ kí àyà fò yín; nítorí pé, OLUWA Ọlọrun yín ń ba yín lọ. Kò ní já yín kulẹ̀, bẹ́ẹ̀ ni kò ní fi yín sílẹ̀.”

Ka pipe ipin Diutaronomi 31

Wo Diutaronomi 31:6 ni o tọ