Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 31:14 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA Ọlọrun sọ fún Mose pé, “Àkókò ń tó bọ̀ tí o óo kú, pe Joṣua, kí ẹ̀yin mejeeji wá sinu àgọ́ àjọ kí n lè fi ohun tí yóo ṣe lé e lọ́wọ́.” Mose ati Joṣua bá wọ inú àgọ́ àjọ lọ.

Ka pipe ipin Diutaronomi 31

Wo Diutaronomi 31:14 ni o tọ