Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 31:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí àwọn ọmọ wọn tí kò tíì mọ̀ ọ́n lè gbọ́ nípa rẹ̀, kí wọ́n sì lè kọ́ láti bẹ̀rù OLUWA Ọlọrun yín, níwọ̀n ìgbà tí ẹ bá wà lórí ilẹ̀ tí ẹ̀ ń rékọjá lọ sí òkè odò Jọdani láti gbà.”

Ka pipe ipin Diutaronomi 31

Wo Diutaronomi 31:13 ni o tọ