Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 30:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ fẹ́ràn OLUWA Ọlọrun yín, ẹ máa gbọ́ tirẹ̀, kí ẹ sì máa súnmọ́ ọn pẹ́kípẹ́kí, kí ẹ lè wà láàyè, kí ẹ lè pẹ́ láyé, kí ẹ sì lè máa gbé orí ilẹ̀ tí OLUWA búra láti fún àwọn baba yín, àní Abrahamu, Isaaki, ati Jakọbu.”

Ka pipe ipin Diutaronomi 30

Wo Diutaronomi 30:20 ni o tọ