Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 30:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo fi ilẹ̀ ati ọ̀run ṣe ẹlẹ́rìí níwájú yín lónìí, pé mo fun yín ní anfaani láti yan ikú tabi ìyè, ati láti yan ibukun tabi ègún. Nítorí náà, ẹ yan ìyè kí ẹ̀yin ati àwọn ọmọ yín lè wà láàyè.

Ka pipe ipin Diutaronomi 30

Wo Diutaronomi 30:19 ni o tọ