Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 3:28-29 BIBELI MIMỌ (BM)

28. Ṣugbọn pàṣẹ fún Joṣua, mú un lọ́kàn le, kí o sì kì í láyà; nítorí pé, òun ni yóo ṣiwaju àwọn eniyan wọnyi lọ, tí wọn yóo fi gba ilẹ̀ tí o óo rí.’

29. “Nítorí náà a bá dúró sí àfonífojì, ní òdìkejì Betipeori.”

Ka pipe ipin Diutaronomi 3