Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 3:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn pàṣẹ fún Joṣua, mú un lọ́kàn le, kí o sì kì í láyà; nítorí pé, òun ni yóo ṣiwaju àwọn eniyan wọnyi lọ, tí wọn yóo fi gba ilẹ̀ tí o óo rí.’

Ka pipe ipin Diutaronomi 3

Wo Diutaronomi 3:28 ni o tọ