Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 3:20 BIBELI MIMỌ (BM)

títí tí OLUWA yóo fi fún àwọn arakunrin yín ní ìsinmi bí ó ti fún yín, tí àwọn náà yóo wà lórí ilẹ̀ tí OLUWA Ọlọrun yín fun wọn ní òdìkejì odò Jọdani. Nígbà náà ni olukuluku yín yóo to pada sórí ilẹ̀ tí mo ti fun yín.’

Ka pipe ipin Diutaronomi 3

Wo Diutaronomi 3:20 ni o tọ