Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 3:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Jairi láti inú ẹ̀yà Manase ni ó gba gbogbo agbègbè Arigobu tí à ń pè ní Baṣani, títí dé etí ààlà ilẹ̀ àwọn Geṣuri, ati ti àwọn Maakati. Ó sọ àwọn ìlú náà ní orúkọ ara rẹ̀; ó pè wọ́n ní Hafoti Jairi. Orúkọ náà ni wọ́n ń jẹ́ títí di òní olónìí.)

Ka pipe ipin Diutaronomi 3

Wo Diutaronomi 3:14 ni o tọ