Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 3:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìdajì tí ó kù lára ilẹ̀ àwọn ará Gileadi, ati gbogbo ilẹ̀ àwọn ará Baṣani tíí ṣe ìjọba Ogu, ati gbogbo agbègbè Arigobu, ni mo fún ìdajì ẹ̀yà Manase.”(Gbogbo ilẹ̀ Baṣani ni wọ́n ń pè ní ilẹ̀ àwọn Refaimu.

Ka pipe ipin Diutaronomi 3

Wo Diutaronomi 3:13 ni o tọ