Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 29:1 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA pàṣẹ fún Mose pé kí ó bá àwọn ọmọ Israẹli dá majẹmu mìíràn ní ilẹ̀ Moabu, yàtọ̀ sí èyí tí ó ti bá wọn dá ní òkè Horebu.

Ka pipe ipin Diutaronomi 29

Wo Diutaronomi 29:1 ni o tọ