Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 25:5 BIBELI MIMỌ (BM)

“Bí àwọn arakunrin meji bá jùmọ̀ ń gbé pọ̀, tí ọ̀kan ninu wọn sì kú láìní ọmọkunrin, aya ẹni tí ó kú kò gbọdọ̀ lọ fẹ́ ará ìta tabi àlejò. Arakunrin ọkọ rẹ̀ ni ó gbọdọ̀ ṣú u lópó, kí ó sì máa ṣe gbogbo ẹ̀tọ́ tí ó bá yẹ fún obinrin náà.

Ka pipe ipin Diutaronomi 25

Wo Diutaronomi 25:5 ni o tọ