Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 23:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Níwọ̀n ìgbà tí ẹ bá ti fínnúfẹ́dọ̀ jẹ́jẹ̀ẹ́ ohunkohun fún OLUWA Ọlọrun yín, ẹ ti fi ẹnu yín ṣèlérí, ẹ sì níláti rí i pé, ẹ mú ẹ̀jẹ́ náà ṣẹ.

Ka pipe ipin Diutaronomi 23

Wo Diutaronomi 23:23 ni o tọ