Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 22:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Bákan náà ni ẹ níláti ṣe, tí ó bá jẹ́ pé kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ rẹ̀ ni ó sọnù, tabi aṣọ rẹ̀, tabi ohunkohun tí ó bá jẹ́ ti arakunrin yín, tí ó bá sọnù tí ẹ sì rí i. Ẹ kò gbọdọ̀ mójú kúrò bí ẹni pé ẹ kò rí i.

Ka pipe ipin Diutaronomi 22

Wo Diutaronomi 22:3 ni o tọ