Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 22:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ibi tí olówó ẹran ọ̀sìn yìí ń gbé bá jìnnà jù, tabi tí ẹ kò bá mọ ẹni náà, ẹ níláti fa ẹran ọ̀sìn náà wálé, kí ó sì wà lọ́dọ̀ yín títí tí olówó rẹ̀ yóo fi máa wá a kiri. Nígbà tí ó bá ń wá a, ẹ níláti dá a pada fún un.

Ka pipe ipin Diutaronomi 22

Wo Diutaronomi 22:2 ni o tọ