Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 21:15 BIBELI MIMỌ (BM)

“Bí ẹnìkan bá ní iyawo meji, tí ó fẹ́ràn ọ̀kan, tí kò sì fẹ́ràn ekeji, tí àwọn mejeeji bímọ fún un, tí ó bá jẹ́ pé iyawo tí kò fẹ́ràn ni ó bí àkọ́bí ọmọkunrin rẹ̀ fún un,

Ka pipe ipin Diutaronomi 21

Wo Diutaronomi 21:15 ni o tọ