Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 21:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, tí kò bá wù yín mọ́ ẹ níláti fún un láyè kí ó lọ sí ibikíbi tí ó bá wù ú, ṣugbọn ẹ kò gbọdọ̀ tà á bí ẹrú, ẹ kò sì gbọdọ̀ lò ó ní ìlò ẹrú, níwọ̀n ìgbà tí ẹ ti bá a lòpọ̀ rí.

Ka pipe ipin Diutaronomi 21

Wo Diutaronomi 21:14 ni o tọ