Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 14:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí pé, ẹni ìyàsọ́tọ̀ ni yín fún OLUWA Ọlọrun yín, OLUWA ti yàn yín láti jẹ́ eniyan tirẹ̀ láàrin gbogbo àwọn eniyan tí wọ́n wà lórí ilẹ̀ ayé.

Ka pipe ipin Diutaronomi 14

Wo Diutaronomi 14:2 ni o tọ