Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 14:1 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ọmọ ni ẹ jẹ́ fún OLUWA Ọlọrun yín, nítorí náà, ẹ kò gbọdọ̀ fi abẹ ya ara yín lára tabi kí ẹ fá irun yín níwájú nígbà tí ẹ bá ń ṣọ̀fọ̀ ẹni tí ó kú.

Ka pipe ipin Diutaronomi 14

Wo Diutaronomi 14:1 ni o tọ