Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 12:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ibẹ̀ ni ẹ̀yin ati gbogbo ìdílé yín yóo ti jẹun níwájú OLUWA Ọlọrun yín, inú yín yóo sì dùn nítorí gbogbo iṣẹ́ ọwọ́ yín tí OLUWA ti fi ibukun sí.

Ka pipe ipin Diutaronomi 12

Wo Diutaronomi 12:7 ni o tọ