Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 12:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ibẹ̀ ni kí ẹ máa mú gbogbo ẹbọ sísun yín, ati àwọn ẹbọ yòókù wá, ati ìdámẹ́wàá yín, ati ọrẹ àtinúwá yín, ati ẹ̀jẹ́ yín tí ẹ bá jẹ́ fún OLUWA, ati àkọ́bí mààlúù yín, ati ti aguntan yín.

Ka pipe ipin Diutaronomi 12

Wo Diutaronomi 12:6 ni o tọ