Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 12:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ibi tí OLUWA Ọlọrun yín bá yàn pé kí ẹ ti máa sin òun bá jìnnà pupọ sí yín, ẹ mú mààlúù tabi aguntan láti inú agbo ẹran tí OLUWA fi fun yín, kí ẹ pa á bí mo ti pa á láṣẹ fun yín, kí ẹ sì jẹ ohunkohun tí ọkàn yín bá fẹ́ láti jẹ láàrin àwọn ìlú yín.

Ka pipe ipin Diutaronomi 12

Wo Diutaronomi 12:21 ni o tọ