Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 12:11 BIBELI MIMỌ (BM)

ibi tí OLUWA Ọlọrun yín bá yàn láti fi ibùgbé rẹ̀ sí nígbà náà, ni kí ẹ kó gbogbo àwọn nǹkan tí mo pa láṣẹ fun yín wa, ẹbọ sísun yín ati àwọn ẹbọ mìíràn, ìdámẹ́wàá yín, ati ọrẹ, ati gbogbo ẹ̀jẹ́ yín tí ẹ bá jẹ́ fún OLUWA.

Ka pipe ipin Diutaronomi 12

Wo Diutaronomi 12:11 ni o tọ