Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 12:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn nígbà tí ẹ bá rékọjá sí òdìkejì odò Jọdani, tí ẹ sì ń gbé ilẹ̀ tí OLUWA Ọlọrun yín yóo fun yín, nígbà tí ó bá sì fun yín ní ìsinmi, tí ẹ bá bọ́ lọ́wọ́ gbogbo àwọn ọ̀tá tí ó yí yín ká, tí ẹ sì wà ní àìléwu,

Ka pipe ipin Diutaronomi 12

Wo Diutaronomi 12:10 ni o tọ