Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 11:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí ẹ fi kọ́ àwọn ọmọ yín dáradára, ẹ máa fi ṣe ọ̀rọ̀ sọ nígbà tí ẹ bá jókòó ninu ilé yín ati ìgbà tí ẹ bá ń rìn lọ lójú ọ̀nà, ati ìgbà tí ẹ bá dùbúlẹ̀ lórí ibùsùn yín ati nígbà tí ẹ bá dìde.

Ka pipe ipin Diutaronomi 11

Wo Diutaronomi 11:19 ni o tọ