Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 11:18 BIBELI MIMỌ (BM)

“Nítorí náà, ohun tí mo sọ fun yín yìí, ẹ pa á mọ́ sinu ọkàn yín. Ẹ fi ọ̀rọ̀ náà sọ́kàn, ẹ so ó mọ́ ọwọ́ yín gẹ́gẹ́ bí àmì, kí ẹ fi ṣe ọ̀já ìgbàjú, kí ó wà ní agbede meji ojú yín mejeeji.

Ka pipe ipin Diutaronomi 11

Wo Diutaronomi 11:18 ni o tọ