Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 10:4 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA bá kọ àwọn òfin mẹ́wàá tí ó kọ sí ara àwọn tabili àkọ́kọ́ sára àwọn tabili náà, ó sì kó wọn fún mi. Àwọn òfin mẹ́wàá yìí ni OLUWA sọ fun yín lórí òkè láti ààrin iná ní ọjọ́ tí ẹ péjọ sí ẹsẹ̀ òkè náà.

Ka pipe ipin Diutaronomi 10

Wo Diutaronomi 10:4 ni o tọ