Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 1:42 BIBELI MIMỌ (BM)

“OLUWA wí fún mi pé, ‘Kìlọ̀ fún wọn kí wọ́n má gòkè lọ jagun, nítorí pé n kò ní bá wọn lọ; bí bẹ́ẹ̀ kọ́ àwọn ọ̀tá yóo ṣẹgun wọn.’

Ka pipe ipin Diutaronomi 1

Wo Diutaronomi 1:42 ni o tọ