Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 1:41 BIBELI MIMỌ (BM)

“Nígbà náà, ẹ dá mi lóhùn, ẹ ní, ẹ ti ṣẹ̀ sí OLUWA, nítorí náà, ẹ óo dìde, ẹ óo sì lọ jagun, gẹ́gẹ́ bí OLUWA Ọlọrun ti pa á láṣẹ fun yín. Olukuluku yín bá múra láti jagun, gbogbo èrò yín nígbà náà ni pé kò ní ṣòro rárá láti ṣẹgun àwọn tí wọn ń gbé agbègbè olókè náà.

Ka pipe ipin Diutaronomi 1

Wo Diutaronomi 1:41 ni o tọ