Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 1:22 BIBELI MIMỌ (BM)

“Gbogbo yín wá sọ́dọ̀ mi, ẹ sì wí pé, ‘Ẹ jẹ́ kí á rán àwọn eniyan lọ ṣiwaju wa, láti lọ ṣe amí ilẹ̀ náà, kí wọ́n lè wá jábọ̀ fún wa, kí á lè mọ ọ̀nà tí ó yẹ kí á tọ̀, ati àwọn ìlú tí ó yẹ kí á wọ̀.’

Ka pipe ipin Diutaronomi 1

Wo Diutaronomi 1:22 ni o tọ