Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 1:21 BIBELI MIMỌ (BM)

ilẹ̀ náà ni OLUWA Ọlọrun yín tẹ́ kalẹ̀ níwájú yín yìí, mo ní kí ẹ gbéra, kí ẹ lọ gbà á, gẹ́gẹ́ bí OLUWA Ọlọrun àwọn baba ńlá yín ti sọ fun yín. Mo ní kí ẹ má bẹ̀rù rárá, kí ẹ má sì fòyà.

Ka pipe ipin Diutaronomi 1

Wo Diutaronomi 1:21 ni o tọ