Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Daniẹli 9:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo bẹ̀rẹ̀ sí gbadura, mò ń jẹ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀ èmi ati ti àwọn ọmọ Israẹli, eniyan mi, mo kó ẹ̀bẹ̀ mi tọ OLUWA Ọlọrun mi lọ, nítorí òkè mímọ́ rẹ̀.

Ka pipe ipin Daniẹli 9

Wo Daniẹli 9:20 ni o tọ